ORIN SOLOMONI 8:14

ORIN SOLOMONI 8:14 YCE

Yára wá, olùfẹ́ mi, yára bí egbin, tabi ọ̀dọ́ akọ àgbọ̀nrín, sí orí àwọn òkè turari olóòórùn dídùn.