N óo ranti àwọn iṣẹ́ OLUWA, àní, n óo ranti àwọn iṣẹ́ ìyanu ìgbàanì. N óo máa ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ; n óo sì máa ronú lórí àwọn iṣẹ́ ribiribi tí o ṣe. Ọlọrun, mímọ́ ni ọ̀nà rẹ; oriṣa wo ni ó tó Ọlọrun wa? Ìwọ ni Ọlọrun tí ń ṣe ohun ìyanu; o ti fi agbára rẹ hàn láàrin àwọn eniyan.
Kà ORIN DAFIDI 77
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 77:11-14
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò