ORIN DAFIDI 71:19

ORIN DAFIDI 71:19 YCE

Ọlọrun, iṣẹ́ òdodo rẹ kan ojú ọ̀run, ìwọ tí o ṣe nǹkan ńlá, Ọlọrun, ta ni ó dàbí rẹ?