ORIN DAFIDI 71:1-3

ORIN DAFIDI 71:1-3 YCE

OLUWA, ìwọ ni mo sá di; má jẹ́ kí ojú ó tì mí laelae! Gbà mí, kí o sì yọ mí nítorí òdodo rẹ; tẹ́tí sí mi kí o sì gbà mí là! Máa ṣe àpáta ààbò fún mi, jẹ́ odi alágbára fún mi kí o sì gbà mí, nítorí ìwọ ni ààbò ati odi mi.