ORIN DAFIDI 68:8

ORIN DAFIDI 68:8 YCE

ilẹ̀ mì tìtì, ọ̀run pàápàá rọ òjò, níwájú Ọlọrun, Ọlọrun Sinai, àní, níwájú Ọlọrun Israẹli.