ORIN DAFIDI 68:4-5
ORIN DAFIDI 68:4-5 YCE
Ẹ kọrin sí Ọlọrun, ẹ kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ̀, ẹ pòkìkí ẹni tí ń gun ìkùukùu lẹ́ṣin. OLUWA ni orúkọ rẹ̀; ẹ máa yọ̀ níwájú rẹ̀. Baba àwọn aláìníbaba ati olùgbèjà àwọn opó ni Ọlọrun, ní ibùgbé rẹ̀ mímọ́.