ORIN DAFIDI 4:7-8

ORIN DAFIDI 4:7-8 YCE

Ìwọ ti fi ayọ̀ kún ọkàn mi ju ayọ̀ àwọn tí ó rí ọpọlọpọ ọkà ati ọtí waini nígbà ìkórè. N óo dùbúlẹ̀, n óo sì sùn ní alaafia, nítorí ìwọ OLUWA nìkan ni o mú mi wà láìléwu.