ORIN DAFIDI 38:9-10

ORIN DAFIDI 38:9-10 YCE

OLUWA, gbogbo ìfẹ́ ọkàn mi ni o mọ̀, ìmí ẹ̀dùn mi kò sì pamọ́ fún ọ. Àyà mi ń lù pì pì pì, ó rẹ̀ mí láti inú wá; ojú mi sì ti di bàìbàì.