ORIN DAFIDI 25:12

ORIN DAFIDI 25:12 YCE

Ẹni tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni OLUWA yóo kọ́ ní ọ̀nà tí yóo yàn.