Ọkunrin wo li o bẹ̀ru Oluwa? on ni yio kọ́ li ọ̀na ti yio yàn.
Ẹni tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni OLUWA yóo kọ́ ní ọ̀nà tí yóo yàn.
Àwọn wo ni ó bẹ̀rù OLúWA? Yóò kọ́ wọn ní ọ̀nà èyí tí wọn yóò yàn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò