Ẹ yin OLUWA! Ẹ yin Ọlọrun ninu ibi mímọ́ rẹ̀; ẹ yìn ín ninu òfuurufú rẹ̀ tí ó lágbára. Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ ńlá rẹ̀; ẹ yìn ín nítorí pé ó tóbi pupọ. Ẹ fi ariwo fèrè yìn ín; ẹ fi fèrè ati hapu yìn ín. Ẹ fi ìlù ati ijó yìn ín; ẹ fi gòjé ati dùùrù yìn ín. Ẹ fi aro olóhùn òkè yìn ín; ẹ fi aro olóhùn gooro yìn ín.
Kà ORIN DAFIDI 150
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 150:1-5
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò