ORIN DAFIDI 149:6-9

ORIN DAFIDI 149:6-9 YCE

Kí wọn máa fi ohùn wọn yin Ọlọrun; kí idà olójú meji sì wà ní ọwọ́ wọn, láti gbẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, ati láti jẹ àwọn eniyan wọn níyà; láti fi ẹ̀wọ̀n de àwọn ọba orílẹ̀-èdè mìíràn, ati láti fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ de àwọn ọlọ́lá wọn; láti ṣe ìdájọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀. Ògo gbogbo àwọn olódodo nìyí.