ORIN DAFIDI 145:15-16

ORIN DAFIDI 145:15-16 YCE

Ojú gbogbo eniyan ń wò ọ́, o sì fún wọn ní oúnjẹ wọn ní àsìkò. Ìwọ la ọwọ́ rẹ, o sì tẹ́ gbogbo ẹ̀dá alààyè lọ́rùn.