ORIN DAFIDI 130:4-5

ORIN DAFIDI 130:4-5 YCE

Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà, kí á lè máa bẹ̀rù rẹ. Mo gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, àní, mo gbé ọkàn mi lé e, mo sì ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀.