O. Daf 130:4-5
O. Daf 130:4-5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori idariji wà lọdọ rẹ, ki a le ma bẹ̀ru rẹ. Emi duro dè Oluwa, ọkàn mi duro, ati ninu ọ̀rọ rẹ̀ li emi nṣe ireti.
O. Daf 130:4-5 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà, kí á lè máa bẹ̀rù rẹ. Mo gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, àní, mo gbé ọkàn mi lé e, mo sì ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀.