ÌWÉ ÒWE 9:11-12

ÌWÉ ÒWE 9:11-12 YCE

Nípasẹ̀ mi ẹ̀mí rẹ yóo gùn. Ọpọlọpọ ọdún ni o óo sì lò lórí ilẹ̀ alààyè. Bí o bá gbọ́n, o óo jèrè ọgbọ́n rẹ, Bí o bá sì jẹ́ pẹ̀gànpẹ̀gàn, ìwọ nìkan ni o óo jèrè rẹ̀.