ÌWÉ ÒWE 4:25-27

ÌWÉ ÒWE 4:25-27 YCE

Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán, kí o sì kọjú sí ibi tí ò ń lọ tààrà. Kíyèsí ìrìn ẹsẹ̀ rẹ, gbogbo ọ̀nà rẹ yóo sì là. Má ṣe yà sí ọ̀tún tabi sí òsì, yipada kúrò ninu ibi.