ÌWÉ ÒWE 4:21-22

ÌWÉ ÒWE 4:21-22 YCE

Má jẹ́ kí wọn rú ọ lójú, fi wọ́n sọ́kàn. Nítorí pé ìyè ni wọ́n jẹ́ fún àwọn tí ó rí wọn, ati ìwòsàn fún gbogbo ẹran ara wọn.