Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Owe 4:21
Ilana Ọlọrun fun Igbesi aye ati Ilera
7 Awọn ọjọ
Ìfọkànsìn yìí ni a pinnu láti ṣàyẹ̀wò àṣẹ tí baba fún ọmọ rẹ̀ nípa ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ fún ẹran ara. Níhìn-ín, baba ni Ọba Dafidi, ọmọ sì ni Solomoni. Ní ti àwa, baba ni Baba wa ọ̀run, ọmọ sì ń tọ́ka sí gbogbo àwọn tí wọ́n ti gba Jésù gẹ́gẹ́ bí Olúwa àti Olùgbàlà.
Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà Gbogbo
Ọgbọ̀n ọjọ́
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.