ÌWÉ ÒWE 27:10

ÌWÉ ÒWE 27:10 YCE

Má pa àwọn ọ̀rẹ́ rẹ tì ati àwọn ọ̀rẹ́ baba rẹ; má sì lọ sí ilé arakunrin rẹ ní ọjọ́ ìṣòro rẹ. Nítorí pé aládùúgbò tí ó súnmọ́ ni sàn ju arakunrin tí ó jìnnà sí ni lọ.