ÌWÉ ÒWE 21:11-12

ÌWÉ ÒWE 21:11-12 YCE

Ìjìyà ẹlẹ́yà a máa mú kí òpè gbọ́n, tí a bá ń kọ́ ọlọ́gbọ́n, yóo ní ìmọ̀ sí i. Olódodo ṣàkíyèsí ilé eniyan burúkú, eniyan burúkú sì bọ́ sinu ìparun.