ÌWÉ ÒWE 17:24-25

ÌWÉ ÒWE 17:24-25 YCE

Ẹni tí ó ní òye a máa tẹjúmọ́ ọgbọ́n, ṣugbọn ojú òmùgọ̀ kò gbé ibìkan, ó ń wo òpin ilẹ̀ ayé. Òmùgọ̀ ọmọ jẹ́ ìbànújẹ́ baba rẹ̀, ati ọgbẹ́ ọkàn fún ìyá tí ó bí i.