Owe 17:24-25
Owe 17:24-25 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí ó ní òye a máa tẹjúmọ́ ọgbọ́n, ṣugbọn ojú òmùgọ̀ kò gbé ibìkan, ó ń wo òpin ilẹ̀ ayé. Òmùgọ̀ ọmọ jẹ́ ìbànújẹ́ baba rẹ̀, ati ọgbẹ́ ọkàn fún ìyá tí ó bí i.
Pín
Kà Owe 17Owe 17:24-25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọgbọ́n wà niwaju ẹniti o moye; ṣugbọn oju aṣiwère mbẹ li opin ilẹ̀-aiye. Aṣiwère ọmọ ni ibinujẹ baba rẹ̀, ati kikoro ọkàn fun iya ti o bi i.
Pín
Kà Owe 17