ÌWÉ ÒWE 17:19-21

ÌWÉ ÒWE 17:19-21 YCE

Ẹni tí ó bá fẹ́ràn ìjà fẹ́ràn ẹ̀ṣẹ̀, ẹni tí ó bá fẹ́ràn kí á máa fi owó ṣe àṣehàn ń wá ìparun. Ẹni tí ó ní ọkàn ẹ̀tàn kò ní ṣe àṣeyege, ẹlẹ́nu meji yóo bọ́ sinu ìyọnu. Ìbànújẹ́ ni kí eniyan bí ọmọ tí kò gbọ́n, kò sí ayọ̀ fún baba òmùgọ̀.