ÌWÉ ÒWE 17:17-18

ÌWÉ ÒWE 17:17-18 YCE

Ọ̀rẹ́ a máa fẹ́ni nígbà gbogbo, ṣugbọn a bí arakunrin láti dúró tini ní ìgbà ìpọ́njú. Ẹni tí kò bá gbọ́n níí jẹ́jẹ̀ẹ́, láti ṣe onídùúró fún aládùúgbò rẹ̀.