Owe 17:17-18
Owe 17:17-18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọrẹ́ a ma fẹni nigbagbogbo, ṣugbọn arakunrin li a bi fun ìgba ipọnju. Enia ti oye kù fun, a ṣe onigbọwọ, a si fi ara sọfà niwaju ọrẹ́ rẹ̀.
Pín
Kà Owe 17Owe 17:17-18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọrẹ́ a ma fẹni nigbagbogbo, ṣugbọn arakunrin li a bi fun ìgba ipọnju. Enia ti oye kù fun, a ṣe onigbọwọ, a si fi ara sọfà niwaju ọrẹ́ rẹ̀.
Pín
Kà Owe 17Owe 17:17-18 Yoruba Bible (YCE)
Ọ̀rẹ́ a máa fẹ́ni nígbà gbogbo, ṣugbọn a bí arakunrin láti dúró tini ní ìgbà ìpọ́njú. Ẹni tí kò bá gbọ́n níí jẹ́jẹ̀ẹ́, láti ṣe onídùúró fún aládùúgbò rẹ̀.
Pín
Kà Owe 17