ÌWÉ ÒWE 10:28

ÌWÉ ÒWE 10:28 YCE

Ìrètí olódodo yóo yọrí sí ayọ̀, ṣugbọn ìrètí ẹni ibi yóo jásí òfo.