ẸKÚN JEREMAYA 3:22-33

Verse Images for ẸKÚN JEREMAYA 3:22-33

ẸKÚN JEREMAYA 3:22-33 - Nítorí pé Ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀ kò nípẹ̀kun,
àánú rẹ̀ kò sì lópin;
ọ̀tun ni wọ́n láràárọ̀,
òtítọ́ rẹ̀ pọ̀.
Ọkàn mi wí pé, “OLUWA ni ìpín mi,
nítorí náà lọ́dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi wà.”

OLUWA a máa ṣe oore fún àwọn tí wọn dúró dè é,
tí wọn sì ń wá ojurere rẹ̀.
Ó dára kí eniyan dúró jẹ́ẹ́, de ìgbàlà OLUWA.
Ó dára kí eniyan foríti àjàgà ìtọ́sọ́nà ní ìgbà èwe.

Kí ó fi ọwọ́ lẹ́rán, kí ó dákẹ́, kí ó sì máa wòye,
nítorí Ọlọrun ni ó gbé àjàgà náà kọ́ ọ lọ́rùn.
Kí ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀,
bóyá ìrètí lè tún wà fún un.
Kí ó kọ etí rẹ̀ sí ẹni tí ó fẹ́ gbá a létí,
kí wọ́n sì fi àbùkù kàn án.

Nítorí OLUWA kò ní ta wá nù títí lae.
Bí ó tilẹ̀ mú kí ìbànújẹ́ dé bá wa,
yóo ṣàánú wa, yóo tù wá ninu,
gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.
Nítorí pé kì í kàn déédé ni eniyan lára
tabi kí ó mú ìbànújẹ́ dé bá eniyan láìní ìdí.ẸKÚN JEREMAYA 3:22-33 - Nítorí pé Ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀ kò nípẹ̀kun,

tabi kí ó mú ìbànújẹ́ dé bá eniyan láìní ìdí.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú ẸKÚN JEREMAYA 3:22-33