Tí mo bá ti wo oòrùn nígbà tí ó ń ràn, tabi tí mo wo òṣùpá ninu ẹwà rẹ̀: tí ọkàn mi fà sí wọn; tí mo sì tẹ́wọ́ adura sí wọn. Èyí pẹlu yóo jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, tí adájọ́ gbọdọ̀ jẹ mí níyà fún; nítorí yóo jẹ́ aiṣootọ sí Ọlọrun ọ̀run.
Kà JOBU 31
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: JOBU 31:26-28
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò