JOBU 23:11-12

JOBU 23:11-12 YCE

Mò ń tẹ̀lé e lẹ́yìn, mo súnmọ́ ọn pẹ́kípẹ́kí, n kò tíì yipada kúrò ní ọ̀nà rẹ̀. N kò tíì yapa kúrò ninu àṣẹ tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde, mò ń pa wọ́n mọ́ ninu ọkàn mi.