Job 23:11-12
Job 23:11-12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹsẹ mi ti tẹle ipasẹ irin rẹ, ọ̀na rẹ̀ ni mo ti kiyesi, ti nkò si yà kuro. Bẹ̃ni emi kò pada sẹhin kuro ninu ofin ẹnu rẹ̀, emi si pa ọ̀rọ ẹnu rẹ̀ mọ́ jù ofin inu mi lọ.
Pín
Kà Job 23Ẹsẹ mi ti tẹle ipasẹ irin rẹ, ọ̀na rẹ̀ ni mo ti kiyesi, ti nkò si yà kuro. Bẹ̃ni emi kò pada sẹhin kuro ninu ofin ẹnu rẹ̀, emi si pa ọ̀rọ ẹnu rẹ̀ mọ́ jù ofin inu mi lọ.