AISAYA 43:1-2

Verse Images for AISAYA 43:1-2

AISAYA 43:1-2 - Ṣugbọn nisinsinyii, Jakọbu,
gbọ́ nǹkan tí OLUWA ẹlẹ́dàá rẹ wí,
Israẹli, gbọ́ ohun tí ẹni tí ó dá ọ sọ.
Ó ní, “Má bẹ̀rù, nítorí mo ti rà ọ́ pada;
mo ti pè ọ́ ní orúkọ rẹ, èmi ni mo ni ọ́.
Nígbà tí o bá ń la ibú omi kọjá,
n óo wà pẹlu rẹ;
nígbà tí o bá la odò ńlá kọjá,
kò ní bò ọ́ mọ́lẹ̀,
nígbà tí o bá ń kọjá ninu iná, kò ní jó ọ.
Ahọ́n iná kò ní jó ọ run.AISAYA 43:1-2 - Ṣugbọn nisinsinyii, Jakọbu,

Ahọ́n iná kò ní jó ọ run.

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa