ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:7-8

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:7-8 YCE

Ìmọ́lẹ̀ dára, oòrùn sì dùn-ún wò. Bí eniyan ti wù kí ó pẹ́ láyé tó, kí ó máa yọ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, ṣugbọn kí ó ranti pé ọjọ́ tí òun yóo lò ninu ibojì yóo pọ̀ ju èyí tí òun yóo lò láyé lọ. Asán ni ìgbẹ̀yìn gbogbo ohun tí ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀.