1
Saamu 82:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”; ẹ̀yin ní gbogbo ọmọ Ọ̀gá-ògo jùlọ.’
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 82:6
2
Saamu 82:3
Gbèjà àwọn aláìlágbára àti aláìní baba; ṣe ìtọ́jú ẹ̀tọ́ àwọn aláìní àti ẹni ìnilára.
Ṣàwárí Saamu 82:3
3
Saamu 82:4
Gba àwọn aláìlágbára àti aláìní; gbà wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn ènìyàn búburú.
Ṣàwárí Saamu 82:4
4
Saamu 82:8
Dìde, Ọlọ́run, ṣe ìdájọ́ ayé, nítorí gbogbo orílẹ̀-èdè ni ìní rẹ.
Ṣàwárí Saamu 82:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò