1
Saamu 81:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi ni OLúWA Ọlọ́run rẹ, ẹni tí ó mú un yín jáde láti Ejibiti. Ẹ la ẹnu yín gbòòrò, èmi yóò sì kún un.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 81:10
2
Saamu 81:13-14
“Bí àwọn ènìyàn mi yóò bá gbọ́ tèmi bí Israẹli yóò bá tẹ̀lé ọ̀nà mi, Ní kánkán ni èmi yóò ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá wọn kí n sì yí ọwọ́ mi padà sí ọ̀tá wọn!
Ṣàwárí Saamu 81:13-14
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò