1
Saamu 83:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ OLúWA: pé ìwọ nìkan ní Ọ̀gá-ògo jùlọ lórí gbogbo ayé.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 83:18
2
Saamu 83:1
Ọlọ́run, má ṣe dákẹ́; Má ṣe dákẹ́, Ọlọ́run má ṣe dúró jẹ́ẹ́.
Ṣàwárí Saamu 83:1
3
Saamu 83:16
Fi ìtìjú kún ojú wọn, kí àwọn ènìyàn bá à lè ṣe àfẹ́rí orúkọ rẹ àti kí o fi ìjì líle rẹ dẹ́rùbà, ìwọ OLúWA.
Ṣàwárí Saamu 83:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò