1
Òwe 23:24
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Baba olódodo ni yóò yọ̀ gidigidi: ẹni tí ó sì bí ọmọ ọlọ́gbọ́n, yóò ní ayọ̀ nínú rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 23:24
2
Òwe 23:4
Má ṣe ṣe làálàá láti lọ́rọ̀: ṣíwọ́ kúrò nínú ọgbọ́n ara rẹ.
Ṣàwárí Òwe 23:4
3
Òwe 23:18
Nítorí pé ìgbẹ̀yìn ń bẹ nítòótọ́; ìrètí rẹ̀ kì yóò sì gé kúrò.
Ṣàwárí Òwe 23:18
4
Òwe 23:17
Má ṣe jẹ́ kí àyà rẹ ó ṣe ìlara sí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, ṣùgbọ́n kí ìwọ ó wà ní ìbẹ̀rù OLúWA, ní ọjọ́ gbogbo.
Ṣàwárí Òwe 23:17
5
Òwe 23:13
Má ṣe fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kúrò lára ọmọdé, nítorí pé bí ìwọ bá fi pàṣán nà án, òun kì yóò kú.
Ṣàwárí Òwe 23:13
6
Òwe 23:12
Fi àyà sí ẹ̀kọ́, àti etí rẹ sí ọ̀rọ̀-ìmọ̀.
Ṣàwárí Òwe 23:12
7
Òwe 23:5
Ìwọ ó ha fi ojú rẹ lépa ohun tí kò sí? Nítorí tí ọ̀rọ̀ hu ìyẹ́ apá fún ara rẹ̀, ó sì ń fò bí idì ní ojú ọ̀run.
Ṣàwárí Òwe 23:5
8
Òwe 23:22
Fetí sí ti baba rẹ tí ó bí ọ, má sì ṣe gan ìyá rẹ, nígbà tí o bá gbó
Ṣàwárí Òwe 23:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò