Owe 23:24
Owe 23:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Baba olododo ni yio yọ̀ gidigidi: ẹniti o si bi ọmọ ọlọgbọ́n, yio ni ayọ̀ ninu rẹ̀.
Pín
Kà Owe 23Owe 23:24 Yoruba Bible (YCE)
Baba olódodo ọmọ yóo láyọ̀ pupọ, inú ẹni tí ó bí ọlọ́gbọ́n ọmọ yóo dùn.
Pín
Kà Owe 23