1
Òwe 24:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nípa ọgbọ́n ni ilé di kíkọ́ nípa òye sì ni ó ti fìdímúlẹ̀
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 24:3
2
Òwe 24:17
Má ṣe yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú; nígbà tí ó bá kọsẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yọ̀.
Ṣàwárí Òwe 24:17
3
Òwe 24:33-34
oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi Òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè àti àìní bí olè.
Ṣàwárí Òwe 24:33-34
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò