1
Owe 31:30
Bibeli Mimọ
Oju daradara li ẹ̀tan, ẹwà si jasi asan: ṣugbọn obinrin ti o bẹ̀ru Oluwa, on ni ki a fi iyìn fun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 31:30
2
Owe 31:25-26
Agbara ati iyìn li aṣọ rẹ̀; on o si yọ̀ si ọjọ ti mbọ. O fi ọgbọ́n yà ẹnu rẹ̀; ati li ahọn rẹ̀ li ofin iṣeun.
Ṣàwárí Owe 31:25-26
3
Owe 31:20
O nà ọwọ rẹ̀ si talaka; nitõtọ, ọwọ rẹ̀ si kàn alaini.
Ṣàwárí Owe 31:20
4
Owe 31:10
Tani yio ri obinrin oniwà rere? nitoriti iye rẹ̀ kọja iyùn.
Ṣàwárí Owe 31:10
5
Owe 31:31
Fi fun u ninu eso-iṣẹ ọwọ rẹ̀; jẹ ki iṣẹ ọwọ ara rẹ̀ ki o si yìn i li ẹnu-bodè.
Ṣàwárí Owe 31:31
6
Owe 31:28
Awọn ọmọ rẹ̀ dide, nwọn si pè e li alabukúnfun, ati bãle rẹ̀ pẹlu, on si fi iyìn fun u.
Ṣàwárí Owe 31:28
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò