1
Owe 30:5
Bibeli Mimọ
Gbogbo ọ̀rọ Oluwa jẹ́ otitọ: on li asà fun gbogbo awọn ti o gbẹkẹ wọn le e.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 30:5
2
Owe 30:8
Mu asan ati eke jìna si mi: máṣe fun mi li òṣi, máṣe fun mi li ọrọ̀; fi onjẹ ti o to fun mi bọ mi.
Ṣàwárí Owe 30:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò