1
AISAYA 64:4
Yoruba Bible
Láti ìgbà àtijọ́, ẹnìkan kò gbọ́ rí, bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò tíì fi ojú rí Ọlọrun mìíràn lẹ́yìn rẹ, tí ń ṣe irú nǹkan wọnyi fún àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé e.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 64:4
2
AISAYA 64:8
Sibẹsibẹ OLUWA, ìwọ ni baba wa, amọ̀ ni wá, ìwọ sì ni amọ̀kòkò; iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.
Ṣàwárí AISAYA 64:8
3
AISAYA 64:6
Gbogbo wa dàbí aláìmọ́, gbogbo iṣẹ́ òdodo wa dàbí àkísà ẹlẹ́gbin. Gbogbo wa rọ bí ewé, àìdára wa sì ń fẹ́ wa lọ bí atẹ́gùn.
Ṣàwárí AISAYA 64:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò