Isa 64:8
Isa 64:8 Yoruba Bible (YCE)
Sibẹsibẹ OLUWA, ìwọ ni baba wa, amọ̀ ni wá, ìwọ sì ni amọ̀kòkò; iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.
Pín
Kà Isa 64Isa 64:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn nisisiyi, Oluwa, iwọ ni baba wa; awa ni amọ̀, iwọ si ni ọ̀mọ; gbogbo wa si ni iṣẹ ọwọ́ rẹ.
Pín
Kà Isa 64