Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Joh 13

Ìtàn Ọjọ Àjínde
Ojó Méje
Bawo ni iwọ yoo ṣe lo ọsẹ ikẹhin ti igbesi aye rẹ ti osi mọ pe o jẹ opin rẹ? Ni ose to koja Jesu wà lori ilẹ ni irisi eniyan ti o kún fun awọn asiko to ṣe iranti, awọn asotele ti o ṣẹ, adura timọtimo, ijiroro jinna, awọn iṣẹ apẹẹrẹ, ati awọn iṣẹlẹ iyipada aye. Ti a ṣe lati bẹrẹ ni Ọjọ-aarọ ṣaaju Ọjọ ajinde, ọjọ kọọkan ti Aye Life.Church eto bibeli n rin ọ nipase itan isọtẹlẹ ti ọsẹ mimọ.

Johannu
Ojó Méwàá
Ètò kekere yìí yóò darí rè kojá lo si Ìhìnrere níbámu pẹ̀lú Jòhánù láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin.

Ìhìnrere Johanu
21 Awọn ọjọ
Nínú ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí, ìwọ yóò bá Ọlọrun Alágbára pàdé – Aṣẹ̀dá ohun gbogbo – tó ní ìrísí ènìyàn, tí a bí láti mú ìgbàlà wá fún gbogbo ènìyàn, níbi gbogbo. Johanu ṣèrántí àwọn iṣẹ́ ìyanu, ẹ̀kọ́ àti àbápàdé ọ̀rẹ́ rẹ tímọ́tímọ́ jùlọ àti Olùgbàlà rẹ, Jesu. A pè ọ́ láti tẹ̀lé Jesu, pẹ̀lú, kí o sì gba ẹ̀bùn ìyè àìnípẹ̀kun Rẹ̀. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.

Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (October)
Ọjọ́ Mòkanlé lọgbọ̀n
Apá kẹwa ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá kẹwa ní àwọn Iwé Oníwàásù, Jòhánù, Jeremaya ati Ẹkun Jeremaya.