Ìhìnrere Johanu

Ọjọ́ 21
Nínú ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí, ìwọ yóò bá Ọlọrun Alágbára pàdé – Aṣẹ̀dá ohun gbogbo – tó ní ìrísí ènìyàn, tí a bí láti mú ìgbàlà wá fún gbogbo ènìyàn, níbi gbogbo. Johanu ṣèrántí àwọn iṣẹ́ ìyanu, ẹ̀kọ́ àti àbápàdé ọ̀rẹ́ rẹ tímọ́tímọ́ jùlọ àti Olùgbàlà rẹ, Jesu. A pè ọ́ láti tẹ̀lé Jesu, pẹ̀lú, kí o sì gba ẹ̀bùn ìyè àìnípẹ̀kun Rẹ̀. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Mount Zion Faith Ministry fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://mountzionfilm.org/