Ìbínú
Ọjọ́ 5
Gbogbo wa la máa n bínú! Ìdáhùn rẹ sí ìbínú dá lórí gbígbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run àti ṣíṣàrò lórí Ọ̀rọ Rẹ̀. Wo ètò kíkà Ìgbẹ́kẹ̀lé lẹ́gbẹ̀ẹ́ àkọ́lé Ìbínú. Àwọn ẹsẹ̀ tí ó tẹ̀lé e, tí a bá fi wọ́n ṣe àkọ́sórí, lè ràn ọ́ l'ọ́wọ́ láti dáhùn sí ìbínú l'ọ́na tó tọ́. Jẹ́ kí ìgbésí ayé rẹ yípadà nípasẹ fífi Ìwé Mímọ́ se àkọ́sórí! Fún ètò kíkún fún fífi Ìwé Mímọ́ se àkọ́sórí, lọ sí www.MemLoK.com
A fẹ́ dúpẹ́ l'ọ́wọ MemLok, Ètò Ìrántí Bíbélì, fún ìpèsè ẹ̀rọ fún ètò yìí. Fún àlàyé síi nípa MemLok, lọ sí: http://www.MemLok.com
Nípa Akéde