1 KọrintiÀpẹrẹ

1 Kọrinti

Ọjọ́ 3 nínú 16

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

1 Kọrinti

Nínù lẹ́tà rẹ̀ àkọ́kọ́ sí àwọn ara Kọrinti, Paulu kojú àwọn ọ̀rọ̀ tó jẹmọ́ ìyapa laarin ìjọ Ọlọrun àti àṣìlò àwọn ẹ̀bùn ẹ̀mí. Ó tún kọ̀wé nípa ìbòrìṣà, ìdánìkanwà, ìgbeyàwó, àgbélébùú, àjínde, àti Ẹ̀mí mímọ́. Bí o bá nílò ọgbọ́n láti lè la àwọn ìrújú inú ìgbàgbọ́ àti ti àwùjọ kọjá, ètò ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí, èyítí YouVersion ṣàgbékalẹ̀ rẹ̀, yóò jẹ́ alábaṣepọ̀ tí yóò ṣèrànlọ́wọ́.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Mount Zion Faith Ministry fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://mountzionfilm.org/