2 Kọrinti
![2 Kọrinti](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F47946%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọjọ́ 13
Lẹ́tà Paulu kejì sí Kọrinti jẹ́ ìṣèwádìí tara-ẹni àti ti oníwàásù nípasẹ̀ àkòrí bíi ìjìyà, ìrẹ́pọ̀, àti ìlawọ́. Paulu fìdí àṣẹ apọsteli rẹ̀ múlẹ̀, ó ṣàlàyé iṣẹ́ ìránṣẹ́ Kristeni tó rán wa létí pé Ọlọrun ńṣàfihàn agbára Rẹ̀ nípasẹ̀ àìlágbára wa. Ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí látọwọ́ YouVersion kọ́ni lọ́gbọ́n fún kíkojú ìpèníjà, fífúrúgbìn ìfaradà ẹ̀mí, àti wíwọ ẹ̀wù ìfẹ́ Kristi tí ńsọni dọ̀tun nínú ayé ìrẹ̀wẹ̀sì yìí.
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Mount Zion Faith Ministry fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://mountzionfilm.org/