Àlàáfíà Olórun

Àlàáfíà Olórun

Ọjọ́ 4

Ọ̀rọ̀ ọlọ́run sọ fún wa wípé óún pèsè àláfíà “èyí tí ó kọjá òye” (Fílípì 4:7 NIV). Nínú ẹ̀kọ́ ọlọ́jọ́-mẹ́rin yíí, ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ma wo àwọn ibi tí atilè rí ìrírí àláfíà yen. Ní ojojúmọ́, fi àdúrà ní kíákíá, kíka ìwé mímọ́ ní ṣhókí àti àlàyé, àṣàyàn iṣẹ́-ṣíṣe, àti àwọn Ìbéèrè ìjíròrò kun.

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹgbẹ́ 'Focus on the Family' fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: www.FocusontheFamily.com
Nípa Akéde