Ohun Tí Baba Sọ

Ọjọ́ 3
Àwọn èrò ìfẹ́ tí Bàbá ní sí ọ pọ̀ ju iyanrìn etí òkun lọ. Ọmọ Rẹ̀ Olùfèẹ́ ni ọ́, inú Rẹ̀ sì dùn sí ọ! Ètò ẹ̀kọ́ ìfọkànsìn yìí jẹ́ ìpé fún ọ láti mọ àbúdà ẹni pípé àti ẹni àgbààyanu tí Bàbá rẹ ọ̀run jẹ́. Nínú ìfẹ́ Rẹ̀, kò sí ìlàkàkà tàbí ìbẹ̀rù, nítorí pé o wà ní àtẹ́lẹwọ́ Rẹ̀.
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Christ for the Nations fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ kàn sí: https://cfni.org/
Nípa Akéde